Ẹkisodu 15:20 BM

20 Nígbà náà ni Miriamu, wolii obinrin, tíí ṣe arabinrin Aaroni, gbé ìlù timbireli lọ́wọ́, gbogbo àwọn obinrin sì tẹ̀lé e, wọ́n ń lu timbireli, wọ́n sì ń jó.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 15

Wo Ẹkisodu 15:20 ni o tọ