21 Miriamu bá dá orin fún wọn pé,“Ẹ kọrin sí OLUWA,nítorí tí ó ti ja àjàṣẹ́gun tí ó lógo,ó ti da ati ẹṣin ati àwọn ẹlẹ́ṣin sinu Òkun Pupa.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 15
Wo Ẹkisodu 15:21 ni o tọ