Ẹkisodu 15:22 BM

22 Mose bá bẹ̀rẹ̀ sí kó àwọn ọmọ Israẹli tẹ̀síwájú láti ibi Òkun Pupa, wọ́n ń lọ sí aṣálẹ̀ Ṣuri, ọjọ́ mẹta ni wọ́n fi rìn ninu aṣálẹ̀ láìrí omi.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 15

Wo Ẹkisodu 15:22 ni o tọ