Ẹkisodu 15:23 BM

23 Nígbà tí wọ́n dé Mara, wọn kò lè mu omi tí wọ́n rí níbẹ̀, nítorí pé ó korò. Nítorí náà, wọ́n sọ orúkọ ibẹ̀ ní Mara, ìtumọ̀ èyí tíí ṣe ìkorò.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 15

Wo Ẹkisodu 15:23 ni o tọ