12 Jẹtiro bá rú ẹbọ sísun sí Ọlọrun. Aaroni ati àwọn àgbààgbà Israẹli sì wá sọ́dọ̀ Jẹtiro, láti bá a jẹun níwájú Ọlọrun.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 18
Wo Ẹkisodu 18:12 ni o tọ