Ẹkisodu 18:13 BM

13 Ní ọjọ́ keji, Mose jókòó, ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìdájọ́ fún àwọn ọmọ Israẹli, àwọn eniyan wà lọ́dọ̀ rẹ̀ láti òwúrọ̀ títí di àṣáálẹ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 18

Wo Ẹkisodu 18:13 ni o tọ