7 Mose bá pada wá, ó pe àwọn àgbààgbà Israẹli jọ, ó sì sọ gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún un fún wọn.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 19
Wo Ẹkisodu 19:7 ni o tọ