8 Gbogbo àwọn eniyan náà bá pa ohùn pọ̀, wọ́n ní, “Gbogbo ohun tí OLUWA wí ni a óo ṣe.” Mose bá lọ sọ ohun tí àwọn eniyan náà wí fún OLUWA.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 19
Wo Ẹkisodu 19:8 ni o tọ