Ẹkisodu 2:12 BM

12 Nígbà tí ó wo ọ̀tún, tí ó wo òsì, tí kò rí ẹnìkankan, ó lu ará Ijipti náà pa, ó sì bò ó mọ́ inú yanrìn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:12 ni o tọ