Ẹkisodu 2:13 BM

13 Nígbà tí ó tún jáde lọ ní ọjọ́ keji, ó rí i tí àwọn Heberu meji ń jà; ó bá bi ẹni tí ó jẹ̀bi pé, “Kí ló dé tí o fi ń lu ẹnìkejì rẹ?”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:13 ni o tọ