Ẹkisodu 20:6 BM

6 Ṣugbọn èmi a máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí ẹgbẹẹgbẹrun àwọn tí wọ́n fẹ́ mi, tí wọ́n sì ń pa òfin mi mọ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 20

Wo Ẹkisodu 20:6 ni o tọ