Ẹkisodu 20:7 BM

7 “O kò gbọdọ̀ pe orúkọ OLUWA Ọlọrun rẹ lásán, nítorí pé, èmi OLUWA yóo dá ẹnikẹ́ni tí ó bá pe orúkọ mi lásán lẹ́bi.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 20

Wo Ẹkisodu 20:7 ni o tọ