Ẹkisodu 21:34 BM

34 ẹni tí ó gbẹ́ kòtò yìí gbọdọ̀ san owó mààlúù tabi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà fún ẹni tí ó ni ín, òkú ẹran yìí yóo sì di ti ẹni tí ó gbẹ́ kòtò.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:34 ni o tọ