Ẹkisodu 21:35 BM

35 Bí mààlúù ẹnìkan bá pa ti ẹlòmíràn, àwọn mejeeji yóo ta mààlúù tí ó jẹ́ ààyè, wọn yóo pín owó rẹ̀, wọn yóo sì pín òkú mààlúù náà pẹlu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:35 ni o tọ