Ẹkisodu 21:36 BM

36 Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ pé mààlúù yìí ti máa ń kàn tẹ́lẹ̀, tí ẹni tí ó ni ín kò sì mú un so, yóo fi mààlúù mìíràn rọ́pò èyí tí mààlúù rẹ̀ pa, òkú mààlúù yóo sì di tirẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 21

Wo Ẹkisodu 21:36 ni o tọ