25 Èmi OLUWA Ọlọrun yín ni kí ẹ máa sìn. N óo pèsè ọpọlọpọ nǹkan jíjẹ ati nǹkan mímu fún yín, n óo sì mú àìsàn kúrò láàrin yín.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 23
Wo Ẹkisodu 23:25 ni o tọ