Ẹkisodu 23:26 BM

26 Ẹyọ oyún kan kò ní bàjẹ́ lára àwọn obinrin yín, bẹ́ẹ̀ ni ẹyọ obinrin kan kò ní yàgàn ninu gbogbo ilẹ̀ yín. N óo jẹ́ kí ẹ gbó, kí ẹ sì tọ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:26 ni o tọ