Ẹkisodu 25:27 BM

27 Kí òrùka kọ̀ọ̀kan súnmọ́ ìgbátí tabili náà, òrùka wọnyi ni wọn yóo máa ti ọ̀pá bọ̀ láti fi gbé tabili náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 25

Wo Ẹkisodu 25:27 ni o tọ