28 Fi igi akasia ṣe ọ̀pá, kí o sì yọ́ wúrà bò wọ́n; àwọn ọ̀pá wọnyi ni wọn yóo máa fi gbé tabili náà.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 25
Wo Ẹkisodu 25:28 ni o tọ