Ẹkisodu 25:29 BM

29 Fi ojúlówó wúrà ṣe àwọn àwo ati àwo kòtò fún turari ati ìgò ati abọ́ tí wọn yóo fi máa ta ohun mímu sílẹ̀ fún ètùtù.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 25

Wo Ẹkisodu 25:29 ni o tọ