Ẹkisodu 26:11 BM

11 Fi idẹ ṣe aadọta ìkọ́, kí o sì fi wọ́n kọ́ àwọn ojóbó náà, láti mú àwọn àránpọ̀ aṣọ mejeeji náà papọ̀ kí wọ́n lè jẹ́ ìbòrí kan.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:11 ni o tọ