10 Ṣe aadọta ojóbó sí awẹ́ tí ó parí àránpọ̀ aṣọ kinni, kí o sì ṣe aadọta ojóbó sí etí awẹ́ tí ó parí aṣọ àránpọ̀ keji.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 26
Wo Ẹkisodu 26:10 ni o tọ