Ẹkisodu 26:9 BM

9 Rán marun-un ninu àwọn aṣọ náà pọ̀, lẹ́yìn náà, rán mẹfa yòókù pọ̀, kí o ṣẹ́ aṣọ kẹfa po bo iwájú àgọ́ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:9 ni o tọ