Ẹkisodu 28:11 BM

11 Bí oníṣẹ́ ọnà wúrà ti máa ń kọ orúkọ sí ara òrùka èdìdì, ni kí o kọ orúkọ àwọn ọmọ Israẹli sí ara òkúta mejeeji, kí o sì fi wúrà ṣe ìtẹ́lẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 28

Wo Ẹkisodu 28:11 ni o tọ