Ẹkisodu 28:12 BM

12 Lẹ́yìn náà, rán àwọn òkúta mejeeji mọ́ àwọn èjìká efodu náà, gẹ́gẹ́ bí òkúta ìrántí fún àwọn ọmọ Israẹli. Èyí yóo mú kí Aaroni máa mú orúkọ wọn wá siwaju OLUWA fún ìrántí.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 28

Wo Ẹkisodu 28:12 ni o tọ