Ẹkisodu 29:33 BM

33 Wọn yóo jẹ àwọn nǹkan tí wọ́n fi ṣe ètùtù láti yà wọ́n sọ́tọ̀ ati láti yà wọ́n sí mímọ́, eniyan tí kì í bá ṣe alufaa kò gbọdọ̀ jẹ ninu rẹ̀, nítorí pé mímọ́ ni wọ́n.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:33 ni o tọ