Ẹkisodu 29:34 BM

34 Bí ẹran ìyàsímímọ́ ati burẹdi náà bá kù di òwúrọ̀ ọjọ́ keji, fi iná sun ìyókù, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ jẹ ẹ́ nítorí pé mímọ́ ni.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:34 ni o tọ