Ẹkisodu 3:11 BM

11 Ṣugbọn Mose dá Ọlọrun lóhùn pé, “Ta ni mo jẹ́, tí n óo fi wá tọ Farao lọ pé mo fẹ́ kó àwọn ọmọ Israẹli kúrò ní ilẹ̀ Ijipti?”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 3

Wo Ẹkisodu 3:11 ni o tọ