Ẹkisodu 32:16 BM

16 Iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọrun ni àwọn wàláà òkúta náà, Ọlọrun tìkararẹ̀ ni ó sì fi ọwọ́ ara rẹ̀ kọ ohun tí ó wà lára wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:16 ni o tọ