Ẹkisodu 32:17 BM

17 Bí Joṣua ti gbọ́ ariwo àwọn eniyan náà tí wọn ń ké, ó wí fún Mose pé, “Ariwo ogun wà ninu àgọ́.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:17 ni o tọ