Ẹkisodu 33:10 BM

10 Nígbà tí gbogbo àwọn eniyan bá sì rí ìkùukùu tí ó dàbí òpó yìí, lẹ́nu ọ̀nà àgọ́, gbogbo àwọn eniyan á dìde, olukuluku wọn á sì sin OLUWA ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:10 ni o tọ