Ẹkisodu 33:9 BM

9 Bí Mose bá ti wọ inú àgọ́ àjọ náà lọ, ìkùukùu náà á sọ̀kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òpó, a sì dúró lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ náà. OLUWA yóo sì bá Mose sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:9 ni o tọ