Ẹkisodu 33:22 BM

22 Nígbà tí ògo mi bá ń kọjá lọ, n óo pa ọ́ mọ́ ninu ihò òkúta yìí, n óo sì fi ọwọ́ mi bò ọ́ lójú nígbà tí mo bá ń rékọjá.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:22 ni o tọ