Ẹkisodu 33:23 BM

23 Lẹ́yìn náà, n óo ká ọwọ́ mi kúrò, o óo sì rí àkẹ̀yìnsí mi, ṣugbọn ẹnikẹ́ni kò lè rí ojú mi.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:23 ni o tọ