Ẹkisodu 34:29 BM

29 Nígbà tí Mose sọ̀kalẹ̀ pada ti orí òkè Sinai dé, pẹlu wàláà ẹ̀rí meji lọ́wọ́ rẹ̀, Mose kò mọ̀ pé ojú òun ń dán, ó sì ń kọ mànàmànà, nítorí pé ó bá Ọlọrun sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:29 ni o tọ