Ẹkisodu 34:30 BM

30 Nígbà tí Aaroni, ati àwọn ọmọ Israẹli rí Mose, wọ́n ṣe akiyesi pé ojú rẹ̀ ń kọ mànàmànà, ẹ̀rù sì ń bà wọ́n láti súnmọ́ ọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:30 ni o tọ