Ẹkisodu 36:34 BM

34 Wọ́n yọ́ wúrà bo gbogbo àkànpọ̀ igi náà, wọ́n fi wúrà ṣe ìkọ́ fún àwọn àkànpọ̀ igi náà, wọ́n sì yọ́ wúrà bo àwọn ọ̀pá ìdábùú náà pẹlu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:34 ni o tọ