Ẹkisodu 36:35 BM

35 Aṣọ aláwọ̀ aró, ati ti elése àlùkò, ati aṣọ pupa ati aṣọ funfun onílà tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ ni wọ́n fi ṣe aṣọ àgọ́ náà, wọ́n sì ya àwòrán Kerubu sí i lára.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:35 ni o tọ