Ẹkisodu 36:36 BM

36 Wọ́n fi igi akasia ṣe òpó mẹrin, wọ́n sì yọ́ wúrà bò ó. Wúrà ni wọ́n fi ṣe àwọn ìkọ́ wọn pẹlu, wọ́n sì fi fadaka ṣe ìtẹ́lẹ̀ mẹrin fún àwọn òpó náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:36 ni o tọ