Ẹkisodu 36:9 BM

9 Gígùn aṣọ títa kọ̀ọ̀kan jẹ́ igbọnwọ mejidinlọgbọn, ìbú rẹ̀ sì jẹ́ igbọnwọ mẹrin, gbogbo wọn rí bákan náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 36

Wo Ẹkisodu 36:9 ni o tọ