18 Ẹ̀ka mẹfa ni ó yọ lára ọ̀pá fìtílà náà; mẹta lẹ́gbẹ̀ẹ́ kinni, mẹta lẹ́gbẹ̀ẹ́ keji.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 37
Wo Ẹkisodu 37:18 ni o tọ