Ẹkisodu 37:19 BM

19 Ó ṣe àwọn kinní kan bí òdòdó alimọndi mẹta mẹta sórí ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn ẹ̀ka mẹfẹẹfa tí ó yọ lára ọ̀pá fìtílà náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 37

Wo Ẹkisodu 37:19 ni o tọ