Ẹkisodu 37:20 BM

20 Ife mẹrin ni ó ṣe sórí ọ̀pá fìtílà náà gan-an, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dàbí òdòdó alimọndi pẹlu ìrudi ati ìtànná rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 37

Wo Ẹkisodu 37:20 ni o tọ