Ẹkisodu 37:26 BM

26 Ó yọ́ ojúlówó wúrà bò ó, ati òkè ati ẹ̀gbẹ́ ati abẹ́ rẹ̀, ati ìwo rẹ̀ pẹlu, ó sì fi wúrà ṣe ìgbátí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 37

Wo Ẹkisodu 37:26 ni o tọ