Ẹkisodu 37:27 BM

27 Ó da òrùka wúrà meji meji, ó jó wọn mọ́ abẹ́ ìgbátí pẹpẹ náà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kinni-keji, òrùka wọnyi ni wọn yóo máa ti ọ̀pá bọ̀ láti fi gbé pẹpẹ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 37

Wo Ẹkisodu 37:27 ni o tọ