Ẹkisodu 39:31 BM

31 Wọ́n so aṣọ aláwọ̀ aró tẹ́ẹ́rẹ́ kan mọ́ ọn, láti máa fi so ó mọ́ etí adé náà gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 39

Wo Ẹkisodu 39:31 ni o tọ