Ẹkisodu 39:32 BM

32 Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo iṣẹ́ àgọ́ àjọ náà ṣe parí, àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun gbogbo gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 39

Wo Ẹkisodu 39:32 ni o tọ