Ẹkisodu 4:7 BM

7 Ọlọrun tún ní, “Ti ọwọ́ rẹ bọ abíyá pada.” Mose sì ti ọwọ́ bọ abíyá rẹ̀ pada; nígbà tí ó yọ ọ́ jáde, ọwọ́ rẹ̀ pada sí bí ó ti wà tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 4

Wo Ẹkisodu 4:7 ni o tọ