Ẹkisodu 4:8 BM

8 Ọlọrun ní, “Bí wọn kò bá fẹ́ gbà ọ́ gbọ́, tabi bí wọn kò bá náání àmì ti àkọ́kọ́, ó ṣeéṣe kí wọ́n gba àmì keji yìí gbọ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 4

Wo Ẹkisodu 4:8 ni o tọ