Ẹkisodu 6:8 BM

8 N óo sì ko yín wá sí ilẹ̀ tí mo búra láti fún Abrahamu, ati Isaaki ati Jakọbu; n óo fún yín gẹ́gẹ́ bí ìní, Èmi ni OLUWA.’ ”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:8 ni o tọ